Ẹ́kísódù 29:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Èmi yóò máa gbé láàárín* àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, èmi yóò sì jẹ́ Ọlọ́run wọn.+