-
Nọ́ńbà 16:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Wọ́n dìtẹ̀ Mósè, àwọn àti igba ó lé àádọ́ta (250) ọkùnrin tó jẹ́ ọmọ Ísírẹ́lì, àwọn ìjòyè àpéjọ náà, àwọn tí a yàn nínú ìjọ, àwọn ọkùnrin tó lókìkí.
-