Léfítíkù 10:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ Áárónì, Nádábù àti Ábíhù,+ mú ìkóná wọn, kálukú fi iná sínú rẹ̀, wọ́n sì fi tùràrí+ sórí rẹ̀. Wọ́n wá bẹ̀rẹ̀ sí í rú ẹbọ tí kò yẹ+ níwájú Jèhófà, ohun tí kò pa láṣẹ fún wọn.
10 Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ Áárónì, Nádábù àti Ábíhù,+ mú ìkóná wọn, kálukú fi iná sínú rẹ̀, wọ́n sì fi tùràrí+ sórí rẹ̀. Wọ́n wá bẹ̀rẹ̀ sí í rú ẹbọ tí kò yẹ+ níwájú Jèhófà, ohun tí kò pa láṣẹ fún wọn.