Fílípì 2:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ẹ má ṣe jẹ́ kí ìbínú+ tàbí ìgbéraga+ mú yín ṣe ohunkóhun, àmọ́ ẹ jẹ́ kí ìrẹ̀lẹ̀* máa mú kí ẹ gbà pé àwọn míì sàn jù yín lọ,+
3 Ẹ má ṣe jẹ́ kí ìbínú+ tàbí ìgbéraga+ mú yín ṣe ohunkóhun, àmọ́ ẹ jẹ́ kí ìrẹ̀lẹ̀* máa mú kí ẹ gbà pé àwọn míì sàn jù yín lọ,+