Nọ́ńbà 12:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Jèhófà wá sọ̀ kalẹ̀ wá nínú ọwọ̀n ìkùukùu,*+ ó dúró ní ẹnu ọ̀nà àgọ́, ó sì pe Áárónì àti Míríámù. Àwọn méjèèjì sì bọ́ síwájú. Nọ́ńbà 14:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Síbẹ̀, gbogbo àwọn èèyàn náà sọ pé àwọn máa sọ wọ́n lókùúta.+ Àmọ́ ògo Jèhófà fara han gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì+ lórí àgọ́ ìpàdé.
5 Jèhófà wá sọ̀ kalẹ̀ wá nínú ọwọ̀n ìkùukùu,*+ ó dúró ní ẹnu ọ̀nà àgọ́, ó sì pe Áárónì àti Míríámù. Àwọn méjèèjì sì bọ́ síwájú.
10 Síbẹ̀, gbogbo àwọn èèyàn náà sọ pé àwọn máa sọ wọ́n lókùúta.+ Àmọ́ ògo Jèhófà fara han gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì+ lórí àgọ́ ìpàdé.