Ẹ́kísódù 23:20, 21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 “Màá rán áńgẹ́lì kan ṣáájú yín+ kó lè dáàbò bò yín lójú ọ̀nà, kó sì mú yín wá síbi tí mo ti ṣètò sílẹ̀.+ 21 Kí ẹ fetí sí i, kí ẹ sì ṣègbọràn sí ohùn rẹ̀. Ẹ má ṣọ̀tẹ̀ sí i, torí kò ní dárí ẹ̀ṣẹ̀ yín jì,+ torí pé orúkọ mi wà lára rẹ̀. 1 Kọ́ríńtì 10:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àwọn nǹkan yìí di àpẹẹrẹ fún wa, kí àwọn ohun tó ń ṣeni léṣe má bàa máa wu àwa náà, bó ṣe wù wọ́n.+ 1 Kọ́ríńtì 10:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Bákan náà, kí ẹ má ṣe máa kùn, bí àwọn kan nínú wọn ṣe kùn,+ tí apanirun sì pa wọ́n.+
20 “Màá rán áńgẹ́lì kan ṣáájú yín+ kó lè dáàbò bò yín lójú ọ̀nà, kó sì mú yín wá síbi tí mo ti ṣètò sílẹ̀.+ 21 Kí ẹ fetí sí i, kí ẹ sì ṣègbọràn sí ohùn rẹ̀. Ẹ má ṣọ̀tẹ̀ sí i, torí kò ní dárí ẹ̀ṣẹ̀ yín jì,+ torí pé orúkọ mi wà lára rẹ̀.
6 Àwọn nǹkan yìí di àpẹẹrẹ fún wa, kí àwọn ohun tó ń ṣeni léṣe má bàa máa wu àwa náà, bó ṣe wù wọ́n.+