-
Nọ́ńbà 7:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Ní ọjọ́ kọ̀ọ̀kan, kí ìjòyè kọ̀ọ̀kan mú ọrẹ rẹ̀ wá fún ìyàsímímọ́ pẹpẹ náà, ní ọjọ́ kan tẹ̀ lé òmíràn.”
-
-
Nọ́ńbà 7:36Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
36 Ní ọjọ́ karùn-ún, Ṣẹ́lúmíẹ́lì+ ọmọ Súríṣádáì, ìjòyè àwọn ọmọ Síméónì,
-