Diutarónómì 9:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “Rántí, má sì gbàgbé bí o ṣe múnú bí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ní aginjù.+ Láti ọjọ́ tí ẹ ti kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì títí ẹ fi dé ibí yìí lẹ ti ń ṣọ̀tẹ̀ sí Jèhófà.+ Diutarónómì 31:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Torí mo mọ̀ dáadáa pé ọlọ̀tẹ̀ ni yín,+ ẹ sì lágídí.*+ Tí ẹ bá ń ṣọ̀tẹ̀ sí Jèhófà tó báyìí nígbà tí mo ṣì wà láàyè pẹ̀lú yín, tí mo bá wá kú ńkọ́!
7 “Rántí, má sì gbàgbé bí o ṣe múnú bí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ní aginjù.+ Láti ọjọ́ tí ẹ ti kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì títí ẹ fi dé ibí yìí lẹ ti ń ṣọ̀tẹ̀ sí Jèhófà.+
27 Torí mo mọ̀ dáadáa pé ọlọ̀tẹ̀ ni yín,+ ẹ sì lágídí.*+ Tí ẹ bá ń ṣọ̀tẹ̀ sí Jèhófà tó báyìí nígbà tí mo ṣì wà láàyè pẹ̀lú yín, tí mo bá wá kú ńkọ́!