-
Léfítíkù 24:2, 3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 “Pàṣẹ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé kí wọ́n gbé ògidì òróró ólífì tí wọ́n fún wá sọ́dọ̀ rẹ láti máa fi tan iná, kí àwọn fìtílà náà lè máa wà ní títàn nígbà gbogbo.+ 3 Lẹ́yìn òde aṣọ ìdábùú Ẹ̀rí nínú àgọ́ ìpàdé, kí Áárónì ṣètò bí àwọn fìtílà náà á ṣe máa wà ní títàn níwájú Jèhófà nígbà gbogbo láti ìrọ̀lẹ́ di òwúrọ̀. Àṣẹ tí gbogbo ìran yín á máa tẹ̀ lé títí láé ni.
-
-
Nọ́ńbà 3:32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 Olórí ìjòyè àwọn ọmọ Léfì ni Élíásárì+ ọmọ àlùfáà Áárónì, òun ló ń darí àwọn tó ń bójú tó iṣẹ́ ní ibi mímọ́.
-