Nọ́ńbà 10:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó àwọn ọmọ Éfúrémù náà gbéra ní àwùjọ-àwùjọ,* Élíṣámà+ ọmọ Ámíhúdù sì ni olórí àwùjọ náà.
22 Ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó àwọn ọmọ Éfúrémù náà gbéra ní àwùjọ-àwùjọ,* Élíṣámà+ ọmọ Ámíhúdù sì ni olórí àwùjọ náà.