-
Léfítíkù 27:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Tí wọ́n bá yọ̀ǹda ilẹ̀ náà lọ́dún Júbílì, yóò di ohun mímọ́ fún Jèhófà, ilẹ̀ tí wọ́n yà sọ́tọ̀ fún un. Ó máa di ohun ìní àwọn àlùfáà.+
-