-
Ẹ́kísódù 13:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Kí ẹ fi àgùntàn ra gbogbo àkọ́bí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ pa dà, tí ẹ ò bá sì rà á pa dà, kí ẹ ṣẹ́ ọrùn rẹ̀. Kí ẹ sì ra gbogbo àkọ́bí nínú àwọn ọmọkùnrin yín pa dà.+
-