-
Léfítíkù 27:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Tó bá jẹ́ ọmọ oṣù kan sí ọdún márùn-ún, kí iye tí wọ́n máa dá lé ọkùnrin jẹ́ ṣékélì fàdákà márùn-ún, kí ti obìnrin sì jẹ́ ṣékélì fàdákà mẹ́ta.
-