Léfítíkù 3:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Kí àlùfáà mú kó rú èéfín lórí pẹpẹ bí oúnjẹ, ọrẹ àfinásun tó máa mú òórùn dídùn* jáde ló jẹ́. Ti Jèhófà ni gbogbo ọ̀rá.+
16 Kí àlùfáà mú kó rú èéfín lórí pẹpẹ bí oúnjẹ, ọrẹ àfinásun tó máa mú òórùn dídùn* jáde ló jẹ́. Ti Jèhófà ni gbogbo ọ̀rá.+