-
Ẹ́kísódù 12:49Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
49 Òfin kan náà ni kí ọmọ ìbílẹ̀ àti àjèjì tó ń gbé láàárín yín máa tẹ̀ lé.”+
-
-
Léfítíkù 24:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 “‘Ìdájọ́ kan náà ni kí ẹ máa tẹ̀ lé, ì báà jẹ́ àjèjì tàbí ọmọ ìbílẹ̀,+ torí èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.’”
-
-
Nọ́ńbà 15:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Àṣẹ kan náà ni kí ìjọ yín àti àjèjì tí ẹ jọ ń gbé máa tẹ̀ lé. Yóò jẹ́ àṣẹ tó máa wà títí lọ, jálẹ̀ àwọn ìran yín. Bákan náà ni kí ẹ̀yin àti àjèjì rí níwájú Jèhófà.+
-