Nọ́ńbà 19:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ẹnikẹ́ni tó bá fara kan òkú èèyàn* máa jẹ́ aláìmọ́ fún ọjọ́ méje.+ Nọ́ńbà 31:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Kí ẹ pàgọ́ sí ẹ̀yìn ibùdó fún ọjọ́ méje. Kí gbogbo ẹ̀yin tí ẹ ti pa èèyàn* àti gbogbo ẹ̀yin tí ẹ ti fara kan ẹni tí wọ́n pa+ wẹ ara yín+ mọ́ ní ọjọ́ kẹta àti ní ọjọ́ keje, ẹ̀yin àti àwọn tí ẹ kó lẹ́rú.
19 Kí ẹ pàgọ́ sí ẹ̀yìn ibùdó fún ọjọ́ méje. Kí gbogbo ẹ̀yin tí ẹ ti pa èèyàn* àti gbogbo ẹ̀yin tí ẹ ti fara kan ẹni tí wọ́n pa+ wẹ ara yín+ mọ́ ní ọjọ́ kẹta àti ní ọjọ́ keje, ẹ̀yin àti àwọn tí ẹ kó lẹ́rú.