Ẹ́kísódù 17:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àwọn èèyàn náà wá bẹ̀rẹ̀ sí í bá Mósè jà,+ wọ́n sì ń sọ pé: “Fún wa lómi mu.” Àmọ́ Mósè bi wọ́n pé: “Kí ló dé tí ẹ̀ ń bá mi jà? Kí ló dé tí ẹ̀ ń dán Jèhófà wò?”+
2 Àwọn èèyàn náà wá bẹ̀rẹ̀ sí í bá Mósè jà,+ wọ́n sì ń sọ pé: “Fún wa lómi mu.” Àmọ́ Mósè bi wọ́n pé: “Kí ló dé tí ẹ̀ ń bá mi jà? Kí ló dé tí ẹ̀ ń dán Jèhófà wò?”+