Ẹ́kísódù 16:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Gbàrà tí Áárónì bá gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sọ̀rọ̀ tán, wọ́n yíjú pa dà, wọ́n sì dojú kọ aginjù. Wò ó! ògo Jèhófà fara hàn nínú ìkùukùu.*+ Nọ́ńbà 14:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Síbẹ̀, gbogbo àwọn èèyàn náà sọ pé àwọn máa sọ wọ́n lókùúta.+ Àmọ́ ògo Jèhófà fara han gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì+ lórí àgọ́ ìpàdé.
10 Gbàrà tí Áárónì bá gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sọ̀rọ̀ tán, wọ́n yíjú pa dà, wọ́n sì dojú kọ aginjù. Wò ó! ògo Jèhófà fara hàn nínú ìkùukùu.*+
10 Síbẹ̀, gbogbo àwọn èèyàn náà sọ pé àwọn máa sọ wọ́n lókùúta.+ Àmọ́ ògo Jèhófà fara han gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì+ lórí àgọ́ ìpàdé.