Àwọn Onídàájọ́ 11:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ísírẹ́lì wá ránṣẹ́ sí ọba Édómù+ pé: “Jọ̀ọ́, jẹ́ ká gba ilẹ̀ rẹ kọjá,” àmọ́ ọba Édómù ò gbà. Wọ́n tún ránṣẹ́ sí ọba Móábù,+ àmọ́ kò gbà. Ísírẹ́lì ò wá kúrò ní Kádéṣì.+
17 Ísírẹ́lì wá ránṣẹ́ sí ọba Édómù+ pé: “Jọ̀ọ́, jẹ́ ká gba ilẹ̀ rẹ kọjá,” àmọ́ ọba Édómù ò gbà. Wọ́n tún ránṣẹ́ sí ọba Móábù,+ àmọ́ kò gbà. Ísírẹ́lì ò wá kúrò ní Kádéṣì.+