Jẹ́nẹ́sísì 15:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ó wá sọ fún Ábúrámù pé: “Mọ̀ dájú pé àwọn ọmọ* rẹ máa di àjèjì ní ilẹ̀ tí kì í ṣe tiwọn, àwọn èèyàn ibẹ̀ á fi wọ́n ṣe ẹrú, wọ́n á sì fìyà jẹ wọ́n fún ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (400) ọdún.+ Ẹ́kísódù 12:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, tó gbé ní Íjíbítì,+ ti lo ọgọ́rùn-ún mẹ́rin ó lé ọgbọ̀n (430) ọdún.+
13 Ó wá sọ fún Ábúrámù pé: “Mọ̀ dájú pé àwọn ọmọ* rẹ máa di àjèjì ní ilẹ̀ tí kì í ṣe tiwọn, àwọn èèyàn ibẹ̀ á fi wọ́n ṣe ẹrú, wọ́n á sì fìyà jẹ wọ́n fún ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (400) ọdún.+