Diutarónómì 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Torí náà, a gba ọ̀dọ̀ àwọn arákùnrin wa kọjá, àwọn àtọmọdọ́mọ Ísọ̀,+ tí wọ́n ń gbé ní Séírì, a ò gba ọ̀nà Árábà, Élátì àti Esioni-gébérì.+ “A wá yí gba ọ̀nà aginjù Móábù.+ Àwọn Onídàájọ́ 11:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Nígbà tí wọ́n rin aginjù, wọn ò gba inú ilẹ̀ Édómù+ àti ilẹ̀ Móábù kọjá. Apá ìlà oòrùn ilẹ̀ Móábù+ ni wọ́n gbà, wọ́n sì pàgọ́ sí agbègbè Áánónì; wọn ò wọnú ààlà Móábù,+ torí Áánónì ni ààlà Móábù.
8 Torí náà, a gba ọ̀dọ̀ àwọn arákùnrin wa kọjá, àwọn àtọmọdọ́mọ Ísọ̀,+ tí wọ́n ń gbé ní Séírì, a ò gba ọ̀nà Árábà, Élátì àti Esioni-gébérì.+ “A wá yí gba ọ̀nà aginjù Móábù.+
18 Nígbà tí wọ́n rin aginjù, wọn ò gba inú ilẹ̀ Édómù+ àti ilẹ̀ Móábù kọjá. Apá ìlà oòrùn ilẹ̀ Móábù+ ni wọ́n gbà, wọ́n sì pàgọ́ sí agbègbè Áánónì; wọn ò wọnú ààlà Móábù,+ torí Áánónì ni ààlà Móábù.