Ẹ́kísódù 6:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Áárónì wá fi Élíṣébà, ọmọ Ámínádábù, arábìnrin Náṣónì+ ṣe aya. Ó bí Nádábù, Ábíhù, Élíásárì àti Ítámárì+ fún un. Nọ́ńbà 4:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “Élíásárì+ ọmọ àlùfáà Áárónì ló ń bójú tó òróró tí wọ́n fi ń tan iná,+ tùràrí onílọ́fínńdà,+ ọrẹ ọkà ìgbà gbogbo àti òróró àfiyanni.+ Òun ló ń bójú tó gbogbo àgọ́ ìjọsìn àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀, títí kan ibi mímọ́ àti àwọn ohun èlò rẹ̀.”
23 Áárónì wá fi Élíṣébà, ọmọ Ámínádábù, arábìnrin Náṣónì+ ṣe aya. Ó bí Nádábù, Ábíhù, Élíásárì àti Ítámárì+ fún un.
16 “Élíásárì+ ọmọ àlùfáà Áárónì ló ń bójú tó òróró tí wọ́n fi ń tan iná,+ tùràrí onílọ́fínńdà,+ ọrẹ ọkà ìgbà gbogbo àti òróró àfiyanni.+ Òun ló ń bójú tó gbogbo àgọ́ ìjọsìn àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀, títí kan ibi mímọ́ àti àwọn ohun èlò rẹ̀.”