-
Nọ́ńbà 3:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 “Fi orúkọ àwọn ọmọkùnrin Léfì sílẹ̀ bí wọ́n ṣe wà nínú agbo ilé bàbá wọn àti ìdílé wọn. Gbogbo ọkùnrin tó jẹ́ ọmọ oṣù kan sókè+ ni kí o forúkọ wọn sílẹ̀.”
-