ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 22:36
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 36 Nígbà tí Bálákì gbọ́ pé Báláámù ti dé, ẹsẹ̀kẹsẹ̀ ló lọ pàdé rẹ̀ ní ìlú Móábù, èyí tó wà ní etí Áánónì, ní ààlà ilẹ̀ náà.

  • Àwọn Onídàájọ́ 11:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Nígbà tí wọ́n rin aginjù, wọn ò gba inú ilẹ̀ Édómù+ àti ilẹ̀ Móábù kọjá. Apá ìlà oòrùn ilẹ̀ Móábù+ ni wọ́n gbà, wọ́n sì pàgọ́ sí agbègbè Áánónì; wọn ò wọnú ààlà Móábù,+ torí Áánónì ni ààlà Móábù.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́