-
Jóṣúà 24:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Bálákì ọmọ Sípórì, ọba Móábù sì dìde, ó bá Ísírẹ́lì jà. Torí náà, ó ránṣẹ́ pe Báláámù ọmọ Béórì pé kó wá gégùn-ún fún yín.+
-
-
Àwọn Onídàájọ́ 11:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Ṣé ìwọ wá sàn ju Bálákì+ ọmọ Sípórì, ọba Móábù lọ ni? Ṣé ó bá Ísírẹ́lì fa ohunkóhun rí, àbí ó bá wọn jà rí?
-