Ẹ́kísódù 15:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ní àkókò yẹn, ẹ̀rù yóò ba àwọn séríkí* Édómù, Àwọn alágbára tó ń ṣàkóso Móábù* yóò gbọ̀n rìrì.+ Ọkàn gbogbo àwọn tó ń gbé ní Kénáánì yóò domi.+ Diutarónómì 2:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Lónìí yìí, màá mú kí ẹ̀rù yín máa ba gbogbo èèyàn tó wà lábẹ́ ọ̀run tí wọ́n bá gbọ́ ìròyìn nípa yín. Ọkàn wọn kò ní balẹ̀, jìnnìjìnnì á sì bò wọ́n* torí yín.’+
15 Ní àkókò yẹn, ẹ̀rù yóò ba àwọn séríkí* Édómù, Àwọn alágbára tó ń ṣàkóso Móábù* yóò gbọ̀n rìrì.+ Ọkàn gbogbo àwọn tó ń gbé ní Kénáánì yóò domi.+
25 Lónìí yìí, màá mú kí ẹ̀rù yín máa ba gbogbo èèyàn tó wà lábẹ́ ọ̀run tí wọ́n bá gbọ́ ìròyìn nípa yín. Ọkàn wọn kò ní balẹ̀, jìnnìjìnnì á sì bò wọ́n* torí yín.’+