-
Jẹ́nẹ́sísì 13:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Jèhófà sọ fún Ábúrámù lẹ́yìn tí Lọ́ọ̀tì kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀ pé: “Jọ̀ọ́ gbójú sókè níbi tí o wà, kí o sì wo àríwá àti gúúsù, ìlà oòrùn àti ìwọ̀ oòrùn,
-