-
Nọ́ńbà 22:32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 Áńgẹ́lì Jèhófà wá sọ fún un pé: “Kí ló dé tí o fi lu kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ lẹ́ẹ̀mẹta yìí? Wò ó! Ṣe ni èmi fúnra mi jáde wá, kí n lè dí ọ lọ́nà, torí pé ohun tí o fẹ́ ṣe ta ko ohun tí mo fẹ́.+
-