Ẹ́kísódù 6:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Élíásárì+ ọmọ Áárónì fi ọ̀kan nínú àwọn ọmọbìnrin Pútíélì ṣe aya. Ó bí Fíníhásì fún un.+ Àwọn ni olórí agbo ilé bàbá àwọn ọmọ Léfì, gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn.+ Diutarónómì 10:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 “Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gbéra ní Béérótì Bene-jáákánì lọ sí Mósírà. Ibẹ̀ ni Áárónì kú sí, ibẹ̀ sì ni wọ́n sin ín sí,+ Élíásárì ọmọ rẹ̀ wá di àlùfáà dípò rẹ̀.+
25 Élíásárì+ ọmọ Áárónì fi ọ̀kan nínú àwọn ọmọbìnrin Pútíélì ṣe aya. Ó bí Fíníhásì fún un.+ Àwọn ni olórí agbo ilé bàbá àwọn ọmọ Léfì, gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn.+
6 “Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gbéra ní Béérótì Bene-jáákánì lọ sí Mósírà. Ibẹ̀ ni Áárónì kú sí, ibẹ̀ sì ni wọ́n sin ín sí,+ Élíásárì ọmọ rẹ̀ wá di àlùfáà dípò rẹ̀.+