-
Nọ́ńbà 22:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Ọlọ́run wá bá Báláámù ní òru, ó sì sọ fún un pé: “Bó bá jẹ́ pé àwọn ọkùnrin yìí fẹ́ kí o tẹ̀ lé àwọn ni, tẹ̀ lé wọn. Àmọ́ ohun tí mo bá sọ fún ọ pé kí o sọ nìkan ni kí o sọ.”+
-