Ẹ́kísódù 6:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Áárónì wá fi Élíṣébà, ọmọ Ámínádábù, arábìnrin Náṣónì+ ṣe aya. Ó bí Nádábù, Ábíhù, Élíásárì àti Ítámárì+ fún un. Ẹ́kísódù 38:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Àwọn nǹkan yìí ni wọ́n kà pé ó wà nínú àgọ́ ìjọsìn, àgọ́ Ẹ̀rí.+ Mósè ló pàṣẹ pé kí àwọn ọmọ Léfì+ kà á, kí Ítámárì ọmọ àlùfáà Áárónì sì darí wọn.+ 1 Kíróníkà 6:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àwọn ọmọ* Ámúrámù+ ni Áárónì,+ Mósè+ àti Míríámù.+ Àwọn ọmọ Áárónì sì ni Nádábù, Ábíhù,+ Élíásárì+ àti Ítámárì.+
23 Áárónì wá fi Élíṣébà, ọmọ Ámínádábù, arábìnrin Náṣónì+ ṣe aya. Ó bí Nádábù, Ábíhù, Élíásárì àti Ítámárì+ fún un.
21 Àwọn nǹkan yìí ni wọ́n kà pé ó wà nínú àgọ́ ìjọsìn, àgọ́ Ẹ̀rí.+ Mósè ló pàṣẹ pé kí àwọn ọmọ Léfì+ kà á, kí Ítámárì ọmọ àlùfáà Áárónì sì darí wọn.+
3 Àwọn ọmọ* Ámúrámù+ ni Áárónì,+ Mósè+ àti Míríámù.+ Àwọn ọmọ Áárónì sì ni Nádábù, Ábíhù,+ Élíásárì+ àti Ítámárì.+