-
Nọ́ńbà 22:35Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
35 Àmọ́ áńgẹ́lì Jèhófà sọ fún Báláámù pé: “Máa tẹ̀ lé àwọn ọkùnrin náà lọ, àmọ́ ohun tí mo bá sọ fún ọ nìkan ni kí o sọ.” Báláámù wá ń bá àwọn ìjòyè Bálákì lọ.
-
-
Nọ́ńbà 23:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Jèhófà fi ọ̀rọ̀ yìí sí Báláámù+ lẹ́nu pé: “Pa dà sọ́dọ̀ Bálákì, ohun tí wàá sì sọ fún un nìyí.”
-