-
Àìsáyà 14:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ti búra pé:
“Bí mo ṣe gbèrò gẹ́lẹ́ ló máa rí,
Ohun tí mo sì pinnu gẹ́lẹ́ ló máa ṣẹ.
-
-
Míkà 7:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 O máa jẹ́ olóòótọ́ sí Jékọ́bù,
Ìfẹ́ tí o ní sí Ábúráhámù kò ní yẹ̀,
Bí o ṣe búra fún àwọn baba ńlá wa láti ìgbà àtijọ́.+
-