Ẹ́kísódù 13:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ní ọ̀sán, Jèhófà máa ń lọ níwájú wọn nínú ọwọ̀n ìkùukùu* kó lè máa darí wọn lójú ọ̀nà,+ àmọ́ ní òru, ó máa ń lọ níwájú wọn nínú ọwọ̀n iná* kó lè fún wọn ní ìmọ́lẹ̀, kí wọ́n lè máa bá ìrìn àjò wọn lọ tọ̀sántòru.+ Ẹ́kísódù 23:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 “Màá rán áńgẹ́lì kan ṣáájú yín+ kó lè dáàbò bò yín lójú ọ̀nà, kó sì mú yín wá síbi tí mo ti ṣètò sílẹ̀.+ Ẹ́kísódù 29:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Èmi yóò máa gbé láàárín* àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, èmi yóò sì jẹ́ Ọlọ́run wọn.+ Àìsáyà 8:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ẹ gbìmọ̀ pọ̀, àmọ́ a máa dà á rú! Ẹ sọ ohun tó wù yín, àmọ́ kò ní yọrí sí rere,Torí Ọlọ́run wà pẹ̀lú wa!*+
21 Ní ọ̀sán, Jèhófà máa ń lọ níwájú wọn nínú ọwọ̀n ìkùukùu* kó lè máa darí wọn lójú ọ̀nà,+ àmọ́ ní òru, ó máa ń lọ níwájú wọn nínú ọwọ̀n iná* kó lè fún wọn ní ìmọ́lẹ̀, kí wọ́n lè máa bá ìrìn àjò wọn lọ tọ̀sántòru.+
20 “Màá rán áńgẹ́lì kan ṣáájú yín+ kó lè dáàbò bò yín lójú ọ̀nà, kó sì mú yín wá síbi tí mo ti ṣètò sílẹ̀.+
10 Ẹ gbìmọ̀ pọ̀, àmọ́ a máa dà á rú! Ẹ sọ ohun tó wù yín, àmọ́ kò ní yọrí sí rere,Torí Ọlọ́run wà pẹ̀lú wa!*+