-
Nọ́ńbà 24:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ọlọ́run ń mú un kúrò ní Íjíbítì.
Ó dà bí ìwo akọ màlúù igbó fún wọn.
Ó máa jẹ àwọn orílẹ̀-èdè run, àwọn tó ń ni ín lára,+
Ó máa jẹ egungun wọn run, ó sì máa fi àwọn ọfà rẹ̀ run wọ́n.
-