-
Nọ́ńbà 22:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Torí náà, àwọn àgbààgbà Móábù àtàwọn àgbààgbà Mídíánì mú owó ìwoṣẹ́ dání, wọ́n rìnrìn àjò lọ sọ́dọ̀ Báláámù,+ wọ́n sì jíṣẹ́ Bálákì fún un.
-