-
Nọ́ńbà 22:38Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
38 Báláámù dá Bálákì lóhùn pé: “Ó dáa, mo ṣáà ti dé báyìí. Àmọ́ ṣé mo wá lè dá sọ ohunkóhun? Ọ̀rọ̀ tí Ọlọ́run bá fi sí mi lẹ́nu+ nìkan ni màá sọ.”
-
-
Nọ́ńbà 23:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Ó dá a lóhùn pé: “Ṣé kí n má sọ ohun tí Jèhófà bá fi sí mi lẹ́nu+ ni?”
-