-
Nọ́ńbà 23:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Bálákì sọ fún un pé: “Jọ̀ọ́, jẹ́ ká lọ sí ibòmíì tí o ti lè rí wọn. Díẹ̀ nínú wọn ni wàá rí; o ò ní rí gbogbo wọn. Bá mi gégùn-ún fún wọn láti ibẹ̀.”+
-