Nọ́ńbà 22:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 ‘Wò ó! Àwọn tó ń jáde bọ̀ láti Íjíbítì bo ilẹ̀.* Wá bá mi gégùn-ún fún wọn.+ Bóyá màá lè bá wọn jà, kí n sì lé wọn kúrò.’”
11 ‘Wò ó! Àwọn tó ń jáde bọ̀ láti Íjíbítì bo ilẹ̀.* Wá bá mi gégùn-ún fún wọn.+ Bóyá màá lè bá wọn jà, kí n sì lé wọn kúrò.’”