Jẹ́nẹ́sísì 49:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ọ̀pá àṣẹ kò ní kúrò lọ́dọ̀ Júdà,+ ọ̀pá aláṣẹ kò sì ní kúrò láàárín ẹsẹ̀ rẹ̀ títí Ṣílò* yóò fi dé,+ òun ni àwọn èèyàn yóò máa ṣègbọràn sí.+ Sáàmù 2:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Á sọ pé: “Èmi fúnra mi ti fi ọba mi jẹ+Lórí Síónì,+ òkè mímọ́ mi.” Jòhánù 1:49 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 49 Nàtáníẹ́lì dá a lóhùn pé: “Rábì, ìwọ ni Ọmọ Ọlọ́run, ìwọ ni Ọba Ísírẹ́lì.”+
10 Ọ̀pá àṣẹ kò ní kúrò lọ́dọ̀ Júdà,+ ọ̀pá aláṣẹ kò sì ní kúrò láàárín ẹsẹ̀ rẹ̀ títí Ṣílò* yóò fi dé,+ òun ni àwọn èèyàn yóò máa ṣègbọràn sí.+