Nọ́ńbà 24:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ó sì sọ̀rọ̀ lówelówe pé: + “Ọ̀rọ̀ Báláámù ọmọ Béórì, Àti ọ̀rọ̀ ẹnu ọkùnrin tí ojú rẹ̀ ti là, 4 Ọ̀rọ̀ ẹni tó ń gbọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run,Tó rí ìran Olódùmarè,Tó wólẹ̀ nígbà tí ojú rẹ̀ là:+
3 Ó sì sọ̀rọ̀ lówelówe pé: + “Ọ̀rọ̀ Báláámù ọmọ Béórì, Àti ọ̀rọ̀ ẹnu ọkùnrin tí ojú rẹ̀ ti là, 4 Ọ̀rọ̀ ẹni tó ń gbọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run,Tó rí ìran Olódùmarè,Tó wólẹ̀ nígbà tí ojú rẹ̀ là:+