Jóṣúà 2:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jóṣúà ọmọ Núnì wá rán ọkùnrin méjì jáde ní bòókẹ́lẹ́ láti Ṣítímù,+ pé kí wọ́n lọ ṣe amí. Ó sọ fún wọn pé: “Ẹ lọ yẹ ilẹ̀ náà wò, pàápàá ilẹ̀ Jẹ́ríkò.” Torí náà, wọ́n lọ, wọ́n dé ilé aṣẹ́wó kan tó ń jẹ́ Ráhábù,+ wọ́n sì dúró sí ibẹ̀. Míkà 6:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ẹ̀yin èèyàn mi, ẹ jọ̀ọ́, ẹ rántí ohun tí Bálákì ọba Móábù gbèrò+Àti ohun tí Báláámù ọmọ Béórì fi dá a lóhùn.+ Ẹ rántí ohun tó ṣẹlẹ̀ láti Ṣítímù+ títí dé Gílígálì,+Kí ẹ lè mọ̀ pé òdodo ni Jèhófà ń ṣe.”
2 Jóṣúà ọmọ Núnì wá rán ọkùnrin méjì jáde ní bòókẹ́lẹ́ láti Ṣítímù,+ pé kí wọ́n lọ ṣe amí. Ó sọ fún wọn pé: “Ẹ lọ yẹ ilẹ̀ náà wò, pàápàá ilẹ̀ Jẹ́ríkò.” Torí náà, wọ́n lọ, wọ́n dé ilé aṣẹ́wó kan tó ń jẹ́ Ráhábù,+ wọ́n sì dúró sí ibẹ̀.
5 Ẹ̀yin èèyàn mi, ẹ jọ̀ọ́, ẹ rántí ohun tí Bálákì ọba Móábù gbèrò+Àti ohun tí Báláámù ọmọ Béórì fi dá a lóhùn.+ Ẹ rántí ohun tó ṣẹlẹ̀ láti Ṣítímù+ títí dé Gílígálì,+Kí ẹ lè mọ̀ pé òdodo ni Jèhófà ń ṣe.”