Nọ́ńbà 25:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nígbà tí Fíníhásì+ ọmọ Élíásárì ọmọ àlùfáà Áárónì rí i, ojú ẹsẹ̀ ló dìde láàárín àpéjọ náà, ó sì mú ọ̀kọ̀* kan dání.
7 Nígbà tí Fíníhásì+ ọmọ Élíásárì ọmọ àlùfáà Áárónì rí i, ojú ẹsẹ̀ ló dìde láàárín àpéjọ náà, ó sì mú ọ̀kọ̀* kan dání.