-
Nọ́ńbà 22:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wá gbéra, wọ́n sì pàgọ́ sí aṣálẹ̀ tó tẹ́jú ní Móábù, ní òdìkejì Jọ́dánì láti Jẹ́ríkò.+
-
-
Nọ́ńbà 33:48Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
48 Níkẹyìn, wọ́n kúrò ní àwọn òkè Ábárímù, wọ́n sì pàgọ́ sí aṣálẹ̀ tó tẹ́jú ní Móábù, lẹ́gbẹ̀ẹ́ Jọ́dánì ní Jẹ́ríkò.+
-