Nọ́ńbà 1:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Kí ìwọ àti Áárónì fi orúkọ gbogbo àwọn tó lè dara pọ̀ mọ́ àwọn ọmọ ogun Ísírẹ́lì sílẹ̀, ní àwùjọ-àwùjọ,* láti ẹni ogún (20) ọdún sókè.+
3 Kí ìwọ àti Áárónì fi orúkọ gbogbo àwọn tó lè dara pọ̀ mọ́ àwọn ọmọ ogun Ísírẹ́lì sílẹ̀, ní àwùjọ-àwùjọ,* láti ẹni ogún (20) ọdún sókè.+