Jẹ́nẹ́sísì 29:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Líà wá lóyún, ó sì bí ọmọkùnrin kan. Ó pe orúkọ rẹ̀ ní Rúbẹ́nì.*+ Ó sọ pé: “Ìdí ni pé Jèhófà ti rí ìyà+ tó ń jẹ mí, ọkọ mi á wá nífẹ̀ẹ́ mi báyìí.”
32 Líà wá lóyún, ó sì bí ọmọkùnrin kan. Ó pe orúkọ rẹ̀ ní Rúbẹ́nì.*+ Ó sọ pé: “Ìdí ni pé Jèhófà ti rí ìyà+ tó ń jẹ mí, ọkọ mi á wá nífẹ̀ẹ́ mi báyìí.”