-
Jẹ́nẹ́sísì 35:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Àwọn ọmọkùnrin tí Líà bí ni Rúbẹ́nì+ tó jẹ́ àkọ́bí Jékọ́bù, lẹ́yìn náà, ó bí Síméónì, Léfì, Júdà, Ísákà àti Sébúlúnì.
-
-
Ẹ́kísódù 6:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Àwọn ọmọ Síméónì ni Jémúélì, Jámínì, Óhádì, Jákínì, Sóhárì àti Ṣéọ́lù ọmọ obìnrin ará Kénáánì.+ Àwọn ni ìdílé Síméónì.
-