-
Nọ́ńbà 1:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 iye àwọn tí wọ́n sì forúkọ wọn sílẹ̀ nínú ẹ̀yà Gádì jẹ́ ẹgbẹ̀rún márùndínláàádọ́ta ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́fà àti àádọ́ta (45,650).