Jẹ́nẹ́sísì 38:2-4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ibẹ̀ ni Júdà ti rí ọmọbìnrin ara Kénáánì+ kan tó ń jẹ́ Ṣúà. Ó mú un, ó bá a lò pọ̀, 3 ó sì lóyún. Lẹ́yìn náà, ó bí ọmọkùnrin kan, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Éérì.+ 4 Ó tún lóyún, ó bí ọmọkùnrin kan, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Ónánì.
2 Ibẹ̀ ni Júdà ti rí ọmọbìnrin ara Kénáánì+ kan tó ń jẹ́ Ṣúà. Ó mú un, ó bá a lò pọ̀, 3 ó sì lóyún. Lẹ́yìn náà, ó bí ọmọkùnrin kan, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Éérì.+ 4 Ó tún lóyún, ó bí ọmọkùnrin kan, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Ónánì.