-
Jẹ́nẹ́sísì 38:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ibẹ̀ ni Júdà ti rí ọmọbìnrin ara Kénáánì+ kan tó ń jẹ́ Ṣúà. Ó mú un, ó bá a lò pọ̀,
-
-
1 Kíróníkà 4:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Àwọn ọmọ Ṣélà+ ọmọ Júdà ni Éérì bàbá Lékà, Láádà bàbá Máréṣà àti àwọn ìdílé àwọn tó ń hun aṣọ àtàtà ti ilé Áṣíbéà,
-